Mark 7:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó tún fi kún un pé, “Àwọn nǹkan tí ń jáde láti inú eniyan ni ó ń sọ ọ́ di aláìmọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wipe, Eyi ti o ti inu enia jade, eyini ni isọ enia di alaimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, ó fi kún un pé: “Èyí ti ó ti ọkàn ènìyàn jáde ni ń sọni di aláìmọ́.