Mark 8:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó bá fi wọ́n sílẹ̀, ó tún wọ inú ọkọ̀ ojú omi, ó lọ sí òdìkejì òkun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi wọn silẹ o si tún bọ sinu ọkọ̀ rekọja lọ si apa ekeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi ó fi àwọn ènìyàn sílẹ̀, ó sì rékọjá sí apákejì òkun náà.