Mark 9:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bi wọ́n pé, “Kí ni ẹ̀yin ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mi ń jiyàn lé lórí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si bi awọn akọwe, wipe, Kili ẹnyin mbère lọwọ wọn?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésù béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Kí ló fa àríyàn-jiyàn?”