Matthew 1:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Josẹfu jí láti ojú oorun, ó ṣe gẹ́gẹ́ bí angẹli Oluwa náà ti pàṣẹ fún un. Ó mú iyawo rẹ̀ sọ́dọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Josefu dide ninu orun rẹ̀, o ṣe bi angẹli Oluwa ti wi fun u, o si mu aya rẹ̀ si ọdọ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Jósẹ́fù jí lójú oorun rẹ̀, òun ṣe gẹ́gẹ́ bí ańgẹ́lì Olúwa ti pàṣẹ fún un. Ó mú Màríà wá sílé rẹ̀ ní aya.