Matthew 1:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kò sì bá a lòpọ̀ rárá títí ó fi bímọ. Ó sì pe orúkọ ọmọ náà ní Jesu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On ko si mọ̀ ọ titi o fi bí akọbi rẹ̀ ọmọkunrin: o si pè orukọ rẹ̀ ni JESU.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n òun kò mọ̀ ọ́n títítí ó fi bí ọmọkùnrin, òun sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Jésù.