Matthew 10:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ẹ bá wọ inú ilé kan lọ, ẹ kí wọn pé, ‘Alaafia fún ilé yìí.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ẹnyin ba si wọ̀ ile kan, ẹ kí i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ẹ̀yin bá sì wọ ilé kan, ẹ kí i wọn.