Matthew 12:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹnu ya gbogbo àwọn eniyan, wọ́n ń wí pé, “Ó ha lè jẹ́ pé ọmọ Dafidi nìyí bí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnu si yà gbogbo enia, nwọn si wipe, Ọmọ Dafidi kọ́ yi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnu sì ya gbogbo àwọn ènìyàn. Wọ́n wí pé, “Èyí ha lè jẹ́ Ọmọ Dáfídì bí?”