Matthew 13:58 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò lè ṣe iṣẹ́ ìyanu pupọ níbẹ̀ nítorí wọn kò ní igbagbọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kò si ṣe ọ̀pọ iṣẹ agbara nibẹ̀, nitori aigbagbọ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà kò se iṣẹ́ ìyanu kankan níbẹ̀, nítorí àìnígbàgbọ́ wọn.