Matthew 14:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba bá ranṣẹ pé kí wọ́n bẹ́ Johanu lórí ninu ẹ̀wọ̀n tí ó wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ranṣẹ lọ, o bẹ́ Johanu li ori ninu tubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, a bẹ́ orí Jòhánù onítẹ̀bọmi nínú ilé túbú.