Matthew 14:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí wọ́n ti wọ inú ọkọ́ ni afẹ́fẹ́ bá rọlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si bọ́ sinu ọkọ̀, afẹfẹ dá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pé, nígbà ti wọ́n sì gòkè sínú ọkọ̀, ìjì náà sì dúró jẹ́ẹ́.