Matthew 14:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn tí wọ́n ti gúnlẹ̀, wọ́n dé ilẹ̀ Genesarẹti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si rekọja si apakeji, nwọn de ilẹ awọn ara Genesareti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọn ré kọjá sí apá kejì wọ́n gúnlẹ̀ sí Gẹ́nẹ́sárẹ́tì.