Matthew 14:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi fi ìbúra ṣe ìlérí láti fún un ní ohunkohun tí ó bá bèèrè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li o ṣe fi ibura ṣe ileri lati fun u li ohunkohun ti o ba bère.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Hẹ́rọ́dù jẹ́ ẹ̀jẹ́ láti fún un ní ohunkóhun ti ó bá béèrè fún.