Matthew 15:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jesu pàṣẹ kí àwọn eniyan jókòó nílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si paṣẹ ki a mu ijọ enia joko ni ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésù sì sọ fún gbogbo ènìyàn kí wọn jókòó lórí ilẹ̀.
Recommended Reading