Matthew 17:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ gbọ́, wọ́n dojúbolẹ̀, ẹ̀rù sì bà wọ́n pupọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ gbọ́, nwọn da oju wọn bolẹ, ẹru si bà wọn gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ti gbọ́ èyí, wọ́n dojú bolẹ̀. Ẹ̀rù sì bà wọ́n gidigidi.