Matthew 18:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn kò gbà; ẹ̀wọ̀n ni ó ní kí wọ́n lọ jù ú sí títí yóo fi san gbèsè tí ó jẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kò si fẹ; o lọ, o gbé e sọ sinu tubu titi yio fi san gbese na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ṣùgbọ́n òun kọ̀ fún un. Ó pàṣẹ kí a mú ọkùnrin náà, kí a sì jù ú sínú túbú títí tí yóò fi san gbésè náà tán pátápátá.