Matthew 19:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Jesu parí àwọn ọ̀rọ̀ wọnyi, ó kúrò ní Galili, ó dé ìgbèríko Judia ní òdìkejì odò Jọdani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati Jesu pari ọ̀rọ wọnyi tan, o kuro ni Galili, o si lọ si ẹkùn Judea li oke odò Jordani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn tí Jésù ti parí ọ̀rọ̀ yìí, ó kúrò ní Gálílì. Ó sì yípo padà sí Jùdíà, ó gba ìhà kejì odò Jọ́dánì.