Matthew 19:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọpọlọpọ tí ó jẹ́ ará iwájú yóo di èrò ẹ̀yìn; àwọn èrò ẹ̀yìn yóo di ará iwájú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ọ̀pọ awọn ti o ṣiwaju ni yio kẹhin; awọn ti o kẹhin ni yio si ṣiwaju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn tí ó ṣíwájú nísinsìn yìí ni yóò kẹ́yìn, àwọn tí ó kẹ́yìn ni yóò sì ṣíwájú.’