Matthew 19:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí ó sì wí pé, ‘Ìdí nìyí tí ọkunrin yóo fi fi baba ati ìyá rẹ́ sílẹ̀ tí yóo fara mọ́ iyawo rẹ̀. Àwọn mejeeji yóo wá di ara kan?’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wipe, Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ, yio famọ́ aya rẹ̀; awọn mejeji a si di ara kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí fún un pé, Nítorí ìdí èyí ‘Ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, òun yóò sí da ara pọ̀ mọ́ aya rẹ̀, àwọn méjèèjì náà á sì di ara kan.’