Matthew 2:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n bí Jesu ní Bẹtilẹhẹmu ní ilẹ̀ Judia, ní ayé Hẹrọdu ọba, àwọn amòye kan wá sí Jerusalẹmu láti ìhà ìlà oòrùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBATI a si bí Jesu ni Betlehemu ti Judea, nigba aiye Herodu ọba, kiyesi, awọn amoye kan ti ìha ìla-õrùn wá si Jerusalemu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ìgbà tí a bí Jésù ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Jùdíà, ni àkókò ọba Hẹ́rọ́dù, àwọn amoye ti ìlà-oòrùn wá sí Jerúsálémù.