Matthew 2:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n rí ìràwọ̀ náà, inú wọn dùn gan-an.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si ri irawọ na, nwọn yọ̀ ayọ nlanla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọ́n sì rí ìràwọ̀ náà, ayọ̀ kún ọkàn wọn.