Matthew 2:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èyí ṣẹlẹ̀ kí ọ̀rọ̀ tí wolii Jeremaya sọ lè ṣẹ pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li eyi ti a ti sọ lati ẹnu woli Jeremiah wa ṣẹ, pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni èyí tí a ti sọ tẹ́lẹ̀ láti ẹnu wòlíì Jeriemáyà wá sẹ pé: