Matthew 20:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n gbà á tán, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí kùn sí ọlọ́gbà àjàrà náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn gbà a tan, nwọn nkùn si bãle na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n ti ń gbà á, wọ́n ń kùn sí onílẹ̀ náà,