Matthew 21:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn èrò tí ń bọ̀ wá sì dá wọn lóhùn pé, “Jesu, wolii, láti ìlú Nasarẹti ti Galili ni.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ijọ enia si wipe, Eyi ni Jesu wolĩ, lati Nasareti ti Galili.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì dáhùn pé, “Èyí ni Jésù, wòlíì náà láti Násárẹ́tì ti Gálílì.”