Matthew 22:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí ọpọlọpọ ni a pè, ṣugbọn àwọn díẹ̀ ni a yàn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọ̀pọlọpọ li a pè, ṣugbọn diẹ li a yàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí ọ̀pọ̀ ni a pè ṣùgbọ́n díẹ̀ ni a yàn.”