Matthew 22:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ekeji náà kú, ati ẹkẹta, títí tí àwọn mejeeje fi kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bẹ̃li ekeji pẹlu, ati ẹkẹta titi o fi de ekeje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ arákùnrin èkejì náà sì tún kú láìlọ́mọ. A sì fi ìyàwó rẹ̀ fún arákùnrin tí ó tún tẹ̀lé e. Bẹ́ẹ̀ sì ni títítí òun fi di ìyàwó ẹnì kéje.