Matthew 22:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ìkẹyìn gbogbo wọn, obinrin náà wá kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nikẹhin gbogbo wọn, obinrin na kú pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níkẹyìn obìnrin náà pàápàá sì kú.