Matthew 23:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ̀yin náà ẹ múra, kí ẹ parí ohun tí àwọn baba yín ṣe kù!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ ẹnyin kuku kún òṣuwọn baba nyin de oke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pé, ẹ̀yin ń tẹ̀lé ìṣísẹ̀ àwọn baba yín. Ẹ̀yin ń kún òsùwọ̀n ìwà búburú wọn dé òkè.