Matthew 24:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tí èyí bá ti ṣẹlẹ̀, kí àwọn tí ó wà ní Judia sálọ sí orí òkè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ki awọn ti mbẹ ni Judea ki o sálọ si ori òke:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, jẹ́ kí àwọn tí ó wà ní Jùdíà sá lọ sí àwọn orí òkè.