Matthew 25:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọlọ́gbọ́n rọ epo sinu ìgò, wọ́n gbé e lọ́wọ́ pẹlu àtùpà wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ọlọgbọn mu oróro ninu kolobo pẹlu fitila wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọlọ́gbọ́n mú epo sínú kólòbó dání pẹ̀lú àtùpà wọn.