Matthew 25:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ọkọ iyawo pẹ́ kí ó tó dé, gbogbo wọn bẹ̀rẹ̀ sí tòògbé, wọ́n bá sùn lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ọkọ iyawo pẹ, gbogbo wọn tõgbé, nwọn si sùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ọkọ ìyàwó pẹ́, gbogbo wọn tòògbé wọn sì sùn.