Matthew 25:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni gbogbo àwọn wundia náà tají, wọ́n tún iná àtùpà wọn ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni gbogbo awọn wundia wọnni dide, nwọn, si tún fitila wọn ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà náà ni àwọn wúńdíá sì tají, wọ́n tún àtùpà wọn ṣe.