Matthew 26:43 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tún wá, ó tún bá àwọn ọmọ-ẹ̀yìn tí wọn ń sùn, nítorí oorun ń kùn wọ́n pupọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wá, o si tun bá wọn, nwọn nsùn: nitoriti oju wọn kun fun orun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó tún padà dé sọ́dọ̀ wọn, Ó rí i pé wọn ń sùn, nítorí ojú wọn kún fún oorun.