Matthew 26:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí títà ni à bá ta òróró yìí ní owó iyebíye tí à bá fi fún àwọn talaka.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A ba sá tà ikunra yi ni owo iyebiye, a ba si fifun awọn talakà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
È é ha ti ṣe, obìnrin yìí ìbá tà á ní owó púpọ̀, kí a sì fi owó náà fún àwọn aláìní.”