Matthew 27:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bá jókòó níbẹ̀, wọ́n ń ṣọ́ ọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si joko, nwọn nṣọ ọ nibẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n jókòó yí i ká. Wọ́n ń ṣọ́ ọ níbẹ̀.