Matthew 27:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Judasi bá da owó náà sílẹ̀ ninu Tẹmpili, ó jáde, ó bá lọ pokùnso.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si dà owo fadaka na silẹ ni tẹmpili, o si jade, o si lọ iso.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Júdásì da owó náà sílẹ̀ nínú tẹ̀ḿpìlì. Ó jáde, ó sì lọ pokùnṣo.