Matthew 27:63 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ní, “Alàgbà, a ranti pé ẹlẹ́tàn nì sọ nígbà tí ó wà láàyè pé lẹ́yìn ọjọ́ mẹta òun óo jí dìde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn wipe, Alàgba, awa ranti pe ẹlẹtan nì wi nigbati o wà lãye pe, Lẹhin ijọ mẹta, emi o jinde.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sọ fún un pé, “Alàgbà, ẹlẹ́tàn náà wí nígbà kan pé, ‘Lẹ́yìn ọjọ́ kẹta èmi yóò tún jí dìde.’