Matthew 28:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀rù mú kí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ibojì náà gbọ̀n pẹ̀pẹ̀, kí wọn sì kú sára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ẹ̀ru rẹ̀ awọn oluṣọ warìri, nwọn si dabi okú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀rù ba àwọn olùṣọ́, wọ́n sì wá rìrì wọn sì dàbí òkú.