Matthew 5:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ebi òdodo ń pa, tí òùngbẹ òdodo sì ń gbẹ, nítorí Ọlọrun yóo bọ́ wọn ní àbọ́yó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alabukún-fun li awọn ẹniti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ sipa ododo: nitori nwọn ó yo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa tí òùngbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó.