Matthew 5:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ọkàn wọn mọ́, nítorí wọn yóo rí Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Alábùkún-fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́, nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run.