Matthew 5:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ó ń mú kí alaafia wà láàrin àwọn eniyan, nítorí Ọlọrun yóo pè wọ́n ní ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alabukún-fun li awọn onilaja: nitori ọmọ Ọlọrun ni a ó ma pè wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Alábùkún-fún ni àwọn tonílàjà, nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n.