Matthew 6:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má fà wá sinu ìdánwò, ṣugbọn gbà wá lọ́wọ́ èṣù.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi. Nitori ijọba ni tirẹ, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ má ṣe fà wá sínú ìdẹwò, Ṣùgbọ́n ẹ gbà wá lọ́wọ́ ibi. Nítorí ìjọba ni tiyín, àti agbára àti ògo, láéláé, Àmín.’