Matthew 9:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jesu bá dìde. Ó ń tẹ̀lé e lọ pẹlu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesu dide, o si ba a lọ, ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésù dìde ó sì bá a lọ àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.