Micah 1:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará Marotu ń retí ire pẹlu gbogbo ọkàn wọn, nítorí pé ibi ti dé sí bodè Jerusalẹmu láti ọ̀dọ̀ OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ara Maroti nreti ire, ṣugbọn ibi sọkalẹ ti ọdọ Oluwa wá si ẹnu bode Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn tí ó ń gbé ni Márátì ń retí ire, Ṣùgbọ́n ibi sọ̀kalẹ̀ ti ọ̀dọ̀ OLÚWA wá sí ẹnu bodè Jérúsálẹ́mù.