Micah 1:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ Jakọbu, ati ti ilé Israẹli ni gbogbo nǹkan wọnyi yóo ṣe ṣẹlẹ̀. Kí ló fa ẹ̀ṣẹ̀ Jakọbu? Ṣebí ìlú Samaria ni. Kí sì ni ẹ̀ṣẹ̀ ilé Juda? Ṣebí ìlú Jerusalẹmu ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori irekọja Jakobu ni gbogbo eyi, ati nitori ẹ̀ṣẹ ile Israeli. Kini irekọja Jakobu? Samaria ha kọ? ki si ni awọn ibi giga Juda? Jerusalemu ha kọ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìré-òfin-kọjá Jákọ́bù ni gbogbo èyí, àti nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì. Kí ni ìré-òfin-kọjá Jákọ́bù? Ǹjẹ́ Samaríà ha kọ? Kí ni àwọn ibi gíga Júdà? Ǹjẹ́ Jérúsálẹ́mù ha kọ?
Recommended Reading