Micah 1:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé egbò Samaria kò lè ṣe é wò jinná; egbò náà sì ti ran Juda, ó ti dé ẹnubodè àwọn eniyan mi, àní, Jerusalẹmu.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ alailewòtan; nitoriti o wá si Juda; on de ẹnu-bode awọn enia mi, ani si Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ aláìlewòtán; ó sì ti wá sí Júdà. Ó sì ti dé ẹnu bodè àwọn ènìyàn mi, àní sí Jérúsálẹ́mù.