Micah 2:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà kò ní sí ìpín fún ẹnikẹ́ni ninu yín mọ́ nígbà tí a bá dá ilẹ̀ náà pada fún àwọn eniyan Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina iwọ kì yio ni ẹnikan ti yio ta okùn nipa ìbo ninu ijọ enia Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ìwọ kò ní ní ẹnìkan kan nínú ìjọ OLÚWA, tí yóò pín ilẹ̀ nípa ìbò.