Micah 3:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí ilé Jakọbu, ati ẹ̀yin alákòóso ilé Israẹli! Ṣé kò yẹ kí ẹ mọ̀ nípa ìdájọ́ òtítọ́?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
EMI si wipe, Gbọ́, emi bẹ̀ nyin, ẹnyin olori ni Jakobu, ati ẹnyin alakoso ile Israeli; ti nyin kì iṣe lati mọ̀ idajọ bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, ni mo wí pé, “Ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí Jákọ́bù, ẹ̀yin alákòóso ilé Ísírẹ́lì. Ǹjẹ́ ẹ̀yin kì í ha ṣe láti mọ òdodo bí.