Micah 5:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ náà, n óo pa àwọn ẹṣin yín run, n óo sì run gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe li ọjọ na, ni Oluwa wi, ti emi o ke awọn ẹṣin rẹ kuro lãrin rẹ, emi o si pa awọn kẹkẹ́ ogun rẹ run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ náà,” ni OLÚWA wí, “Èmi yóò pa àwọn esin rẹ̀ run kúrò láàrin rẹ èmi yóò sì pa àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ run.