Micah 5:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo pa àwọn ìlú tí wọ́n wà lórí ilẹ̀ yín run, n óo sì wó ibi ààbò yín lulẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si ke ilu-nla ilẹ rẹ kuro, emi o si tì gbogbo odi rẹ ṣubu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò sì pa ilẹ̀ ìlú-ńlá rẹ̀ run, èmi ó sì fa gbogbo ibi gíga rẹ̀ ya.