Micah 5:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ibinu ati ìrúnú mi, n óo gbẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè tí wọn kò pa àṣẹ mi mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si gbẹsan ni ibinu ati irunu lara awọn keferi, ti nwọn kò ti igbọ́ ri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò gbẹ̀san ní ìbínú àti ìrunú lórí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò ti tẹríba fún mi.”